Cantigas

Roda de Sango

Kawó Kabiesilé !

Obá wá dodè
Adupé o Obá Wá Dodè
Adupé o !
Adupé ní mó Obá sualé
Adupé ní mó Obá sualé
O, O! pá imà Adupé Ní mó Obá Sualé !

Félé félé Yemanjá wá kum
Yemanjá wá kum arò pá iman
Arò pá iman Adupé kajá wá rò
Wá rò
Osi ajá lé O!

Jambá Jambá
Didè awá nijò
Obá eró fi O!

Orá dada
Agò Larín

Dadá má Kú mã
Dadá má só kú mà
Féré hun féré móbó órum
Dadá fumi lowo gà
Sú má rin

Adè bá ri gui di gui
Bá ri lolá
Adè bá rin a begui
Bá rin Olowo
bá ri gui di gui
Bá ri lo lá

Fura ginà
Obá Fura ginà

Onilé Mo jubá O
Ibá Orisá Ibá
Onilé

Ará in alodè
Bára oni njá oni aroko

Oni ká si ló bó ró
Obá sélubé karajé
Oniká si ló bó ró
Karajé agutan

Etú padè wá Lonà
Oni ká sé relè
Ibò si Ará in Alodè

Ará in alodè
Bára oni njá oni Aroko

Oni ká si ló bó ró
Obá sélubé karajé
Oniká si ló bó ró
Karajé agutan

Etú padè wá Lonà
Oni ka só relè
Ibò si
Ará in Alodè

Ará in Alodè
Bára oni njá oni aroko

Bakò e Bakò
tà ngalá
tà ngalá Onilè korò
e Bakò erú jé jé

Omó ésí éko bele
Eru jé jé Eru jé jé

Omó ésí éko Inà
Eru jé jé
Lodo loko

Eyé Kekerè odò mo ti a
rèrè e lè d'jo masè
Eyé ko ke re ká d'jo kó
Yobá ele d'jo masè

Olowò kò mà bò bò
e kò mà bò
Olowò kò mà bò
Aláfim kó d´jé pá

Awrè Awrè
Awrè urá
Obá adupé
Obá lajò obá korujá
Ahum Ayè

Àyirá Ojú
Kò pè rè sè
Ayo kò pè rè se

Kawó Kabiesilé !